21
A pese re lati owo Ile Ise Eto Inawo, Isuna ati Aato Oro Aje. Olu Ile Ise Ijoba Ipinle Kogi, Lokoja ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN

ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

  • Upload
    others

  • View
    2

  • Download
    0

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

A pese re lati owo Ile Ise Eto Inawo, Isuna ati Aato Oro Aje.

Olu Ile Ise Ijoba Ipinle Kogi, Lokoja

ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN

EGBAA O LE OKOO / OGUN

Page 2: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

AKOPO OHUN TO WA NINU IWE YII

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 1

Ifaara

Iwe to tumo Isuna

Ilana Gbogboogbo

IKADI ISUNA

Nibo ni owo naa yoo ti wa?IKADI AKOJOPO OWO TI IJOBA NGBA

Nibo ni owo naa lo?

02

03-05

06

07

08-09

Bawo ni ijoba yoo se ri eyawo gba?EYAWO ABELE ATI EYAWO OKEERE 10

OWO IFIJINKI ABELE ATI OWO IFIJINKI OKEERE

Bawo ni ijoba yoo se ri owo ifijinki gba?

11-12

Ipin fun ile ise ati eka ijoba to ga ju13-14

AWON AKANSE ISE TO GA JU: ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI

15-18

Page 3: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Oro Akoso

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi

Gege bi a ti mo, eto isuna awa

ara wa je jade lati inu eto isuna

gangan. Nitorinaa, eto isuna

awa ara wa fun odun egbaa o le okoo ni

a fayo lati inu eto isuna ti a fowosi fun

odun egbaa o le okoo. Sugbon, ni

lowolowo yii, akude ti ba oro aje

agbaye nitori igbadi arun korona ti a mo

si COVID-19. Latari eyi, owo epo robi

l agbaye t i j aw a s i l e l a t i b i i

e t a d i n l a a d o r i n d o l a s i d o l a

metadinlogun; beeni sise owo dola

gbera so lati oodunrun naira o le marun

si naira kan si otaleloodunrun dola si

naira kan. Eleyi lo mu ki ijoba fi oju

sunnukun woe to isuna naa lati se

atunyewo re.

Awon ijamba ti arun korona ti se ti mu

ki akude ba oro aje ipinle yii ti o si koba

ona lati le pawo wole labele. Ona a ti

pese awon nkan loniruuru paapaa ti di.

Awon osise ijoba, osise banki ati awon

ile ise miran nsise lati ile won. Eleyi kii

se akoko to pani lerin rara. Nitorinaa, a

gbodo gbe awon igbese akin lati rii pe

isele laabi yii ko so oro aje wa di

akurete. Ijoba nwo awon ona miran lati

ri owo fi se ijoba sugbon eyi le pe die.

Ijoba ipinle yii ti wo sakun abayori

igbadi arun korona yii nipase igbimo

teekoto kan, o si wa mu eto ilera, eto

eko, eto ogbin ati awon inawo

atigbadegba lokunkundun.

Nitori idi eyi, ijoba ti din eto isuna odun

e g b a a o l o o k o o s i b i l i o n u

m e j i l e l o g o r u n , m i l i o n u l o n a

etalelogofa, egberun mokanlelaadorun

ati ojileleedegberun o din mesan naira.

Iye ti apapo eto isuna naa je tele ni

bilionu merindinlogosan, milionu lona

etalelogofa, egberun mokanlelaadorun

ati ojileleedegberun o din mesan naira.

Iye ti a yo kuro ninu re je bilionu

merin le laador in ; e ley i je ida

mejilelogoji ninu ogorun. A o tesiwaju

lati maa dahun leye o soka si eto oro aje

latari arun korona lati rii pe alaafia ati

itura ba awon eniyan wa.

ALHAJI YAHAYA BELLO

GOMINA IPINLE

2

Page 4: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Ifaara

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 3

Ki ni Isuna?

Isuna n se afihan ohun ti ijoba

nreti lati gba gege bi owo to n

wole si apo ijoba; bii owo

atilehin, owo ti a ya; ati pee lo

ni a o fi pamo tabi ya ati ki ni

ijoba nseto lati na owo naa le

lori.

Eto isuna je akosile to nse

apejuwe bi ijoba se n seto lati

na owo ajoni gbogbo ara ilu-

paapaa julo, owo ori. Ijoba

apapo, ijoba ipinle ati ijoba

ibile lo ni eto isuna won labe

ofin.

Ninu ijoba tiwantiwa, gbogbo

omo ilu to duro daadaa lo ni

eto lati mo bi ijoba se n na oro

ajoni ara ilu fun ipese awon

o h u n a m a y e d e r u n f u n

mutunmuwa.ti mo bi ijoba se

n na oro ajoni ara ilu fun ipese

awon ohun amayederun fun

mutunmuwa.

Ki ni Eto Isuna Awa Ara

Wa?

Ki ni Eto Isuna Awa Ara Wa?

Eto isuna awa ara wa je eleyi

to rorun ti ko ni iruju ninu, ti o

si ye gbogbo mutumuwa

yekeyeke. Eto isuna awa ara

wa le je eyi to yato die nipa

ifojusun tabi nipa gigun ati

agbekale re. Sugbon sa, eto

isuna awa ara wa gbodo wa

larowoto gbogbo ara ilu, o si

gbodo wa lori ero ayelujara ti

ijoba.

Apapo Inawo ninu Isuna:

Eleyi ni apapo iye owo ti se

Page 5: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Itupale Awon Oro Ti A Lo Ninu Iwe Eto Isuna Yii

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 4

agbekale re ninu eto isuna fun

odun kan pato. O je apapo

inawo atigbadegba ati inawo

lori ise idagbasoke gege bi ile

igbimo asofin ipinle ba se

gbaa wole ati gege bi Gomina

Ipinle ba se bu owo luu.

Akojopo Owo Ilu: Akojopo

Owo Ilu je gbogbo owo ti ijoba

gbagbo lati ri gba lowo ara ilu

laariin odun latari owo ori ati

awon eto miran fun ijoba.

Ijoba n gba awon owo wonyii

loruko awon ara ilu lati fi pese

awon ohun amayederun.

Elewo Lori Isuna: Eleyi ni

iyato to wa laarin ohun ti

ijoba lero lati na ati iye to

wole gan an. Elewo lori isuna

a maa waye nigba ti iye ti a ba

fen a bap o ju apapo owo ara

ilu ati owo ifijinki.

Owo Ifijinki / Iranlowo: Owo

iranlowo je okan lara ona ti

ijoba fi n ri owo lati fi se awon

ise akanse fun igbe aye irorun

fun awon ara ilu ati lati fi mu ki

oro aje ilu ru gogo sii. Owo

iranlowo yii le wa lati okeere

tabi ni abele. Owo iranlowo kii

se owo ti ya rara ; nitorinaa,

ijoba ko si labe ofin lati da iru

owo bee pada.

Eyawo : Ona miran ti ijoba n

gba lati fi ri owo bojuto eto

isuna ni eyawo. Ijoba a maa

seto eyawo lati fi bojuto eto

isuna laarin odun nigba ti awon

owo ara ilu ati owo iranlowo ko

ba to lati fi gbo bukata isuna.

Eyawo le wa labele tabi lati ile

okeere. Eyawo le je fun awon

Page 6: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Itupale Awon Oro Ti A Lo Ninu Iwe Eto Isuna Yii

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi

ise akanse tabi fun awon

inawo gbogbogbo.

daadaa lo ni eto lati mo bi

ijoba se n na oro ajoni ara ilu

f u n i p e s e a w o n o h u n

amayederun fun mutunmuwa.

Ki ni Eto Isuna Awa Ara Wa?

Eto isuna awa ara wa je eleyi

to rorun ti ko ni iruju ninu, ti o

si ye gbogbo mutumuwa

yekeyeke. Eto isuna awa ara

wa le je eyi to yato die nipa

ifojusun tabi nipa gigun ati

agbekale re. Sugbon sa, eto

isuna awa ara wa gbodo wa

larowoto gbogbo ara ilu, o si

gbodo wa lori ero ayelujara ti

ijoba.

5

Page 7: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

ETO ISUNA LEREFEE

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi

N102.1bnEleyii ni Gbogbo Owo ti Ijoba n sereti lati lo fun isuna.

N91.82bnN10.3bn

BILIONU LONA EJILELOGORUN ATI MILIONU LONA OGORUN

Owo ti ijoba n reti lati gba lowo awon ara ilu ati owo

iranlowo je

BILIONU LONA OKANLELAADORUN O LE MILIONU LONA EJILELOGORUN NAIRA

Elewo lori eto isuna je

BILIONU MEWAA O LE MILIONU LONA

OODUNRUN NAIRA

Isuna ti a fowosiGbogbo Owo ti Ijoba n sereti lati lo fun isuna je: Bilionu lona igba o

din merinlelogun ati milionu lona ogorun naira (N176.1bn)

Owo ti ijoba n reti lati gba lowo awon ara ilu ati owo iranlowo je: Bilionu mokanle laadofa o le milionu lona egbeta naira (N111.6bn).

Elewo lori eto isuna je: Bilionu merinlelogofa o le milionu lona eedegbeta naira (N64.5bn)

7

Page 8: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi

15.04bn

(ForeignLoans): 2.9bn

(Value Added Tax): 11.8bn

(OtherStatutoryRevenue): 1.77bn

(StatutoryAllocation): 29.19bn

(Domestic Grants): 6.37bn

OpeningBalance 24.42bn

(ForeignGrants): 3.23bn

(DomesticLoans): 5.4bn (Sales of

Govt. Assets): 1.9bn

Isuna ti a fowosi

Internally Generated Revenue - N19.04bnStatutory Allocation - N50.43bnValue Added Tax - N17.5bnOther Statutory Revenue - N3.97bnDomestic Grants - N14.39bn

Foreign Grants - N6.28bnDomestic Loans - N28.47bnForeign Loans - N34.06bnSale of Government Assets - N1.99bn

8

Nibo ni Owo naa Yoo ti Wa?Ikadi Apapo Owo Ara Ilu

Owo Apawole Labele (IGR):

BILIONU MARUNDINLOGUN ATI MILIONU LONA IRINWO

NAIRA

Owo Ipinfunni Labe Ofin

BILIONU MOKANDINLOGBON O LE MILIONU LONA

MOKANDINLOGUN NAIRA

Owo Ori

Awon Oja

BILIONU MOKANLA O

LE EGBERIN MILIONU

NAIRA

Awon Owo Apawole Miran Labe Ofin

BILIONU KAN O LE MILIONU

METADINLOGORIN NAIRA

Owo Iranlowo Labele

BILIONU MEFA O LE MILIONU LONA

METADINLOGOJI NAIRA

Owo Iranlowo Lati Okeere

BILIONU META O LE MILIONU LONA

METALELOGUN NAIRA

Eyawo

Labele

BILIONU MARUN O

LE MILIONU LONA

IRINWO NAIRA

Eyawo Lati

Okeere

BILIONU MEJI O LE MILIONU LONA

EEDEGBERUN NAIRA

Tita Awon Ohun Ini Ijoba

BILIONU KAN O LE MILIONU LONA

EEDEGBERUN NAIRA

Page 9: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi

N65.53bn

N102.12bn

N36.6bn

Isuna ti a fowosi

Total Recurrent Expenditure - N77.01bnTotal Capital Expenditure - N99.11bn

9

Inawo: Nibo ni Owo Naa N Lo ?

BILIONU LONA EJILELOGORUN ATI MILIONU LONA OGORUN

Eleyii ni Gbogbo Owo ti Ijoba n sereti lati na fun isuna.

Apapo Inawo

Atigbadegba je:

Bilionu marundinlaadorin o le milionu lona

metalelaadota naira

Apapo Inawo lori Ise Akanse je:

Bilionu merindinlogoji o le milionu lona

egbeta naira

Page 10: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi

Personnel Cost

OverheadCost

N38.2bn N25.46bn

N1.87bn

Isuna ti a fowosiPersonnel Cost - N40.97bnOverhead Cost - N36.04bn

Interest Payments

(Public Debts)

10

Nibo ni Owo naa nlo?

Atupale Inawo

Atigbadegba

Inawo Lori

Awon Osise:

BILIONU LONA MEJIDINLOGOJI O LE MILIONU LONA

IGBA NAIRA

Inawo Ele Lori Isuna:

BILIONU MARUNDINLOGBON O LE MILIONU LONA MERINDINLAADOTA

NAIRA SISAN AWON ELE OWO

LORIN IGBESE:

BILIONU KAN O LE

MILIONU LONA

METADINLAADORUN

NAIRA

Page 11: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 11

Aworan Awon Ibi Ti Owo Naa Nlo

INAWO LORI AWON OSISE

BILIONU LONA MEJIDINLOGOJI, MILIONU LONA IGBA O DIN META, EGBERUN LONA EGBETA O DIN MEJO ATI ORINLENIRINWO O DIN EYOKAN NAIRA (N38,197,592,479)

INAWO ELE LORI ISUNA:

BILIONU LONA METADINLOGBON, MILIONU LONA OODUNRUN O LE METADINLOGBON,

EGBERUN LONA EEDEGBERIN O LE METABINLAADOTA ATI OGBON NAIRA (N27,327,747,030)

ETO OGBIN:

BILIONU MERIN, MILIONU LONA ORINLENIRINWO O DIN EYOKAN ATI EGBERUN

LONA IRINWO O LE MERINDINLAADOTA NAIRA (N4,279,446,000)

BILIONU META, MILIONU LONA AADOJO EGBERUN LONA IRINWO O LE

MOKANLELAADORIN ATI EESANLELEEDEGBERIN NAIRA (N3,150,471,709)

ONA SISE:

BILIONU MARUN, MILIONU LONA ORINLELEGBERIN O LE MARUN ATI EGBERUN LONA EEDEGBETA NAIRA

(N5,885,500,000)

ETO ILERA:

BILIONU MEFA, MILIONU LONA ERINDINLAADOJO, EGBERUN LONA

OTALELOODUNRUN O DIN MERIN ATI EGBERUN O DIN MEJO NAIRA (N6,146,356,992)

IPESE OMI:

BILIONU KAN ATI MILIONU LONA OODUNRUN

O LE MEEDOGBON NAIRA (#1,325,000,000)

INA MANAMANA/IJOBA/ELENTIRIKI:

MILIONU LONA EGBETA O LE METADINLOGBON, EGBERUN MEJILA ATI EGBERIN NAIRA (N627,012,800)

ETO AABO

MILIONU LONA OGORUN O LE MEJILA ATI EGBERUN LONA MEJIDINLAADOTA

NAIRA (#112,048,000)

ODO ATI ERE IDARAYA

MILIONU LONA MERINLELEEDEGBETA ATI EGBERUN LONA ORINLENIRINWO

O DIN MEJO NAIRA (N504,472,000)

OOFIISI ATI ILE'GBE

BILIONU META, MILIONU LONA OJILELEEDEGBERIN O DIN MEWA ATI EGBERUN LONA OODUNRUN O LE

MERINDINLOGUN NAIRA (N3,730,316,000)

ETO IRINNA

BILIONU KAN, MILIONU LONA OTALELEEDEGBERUN O LE MARUN ATI

EGBERUN LONA ORINLENIRINWO NAIRA (N1,965,480,000)

ETO AYIKA

BILIONU MEJI, MILIONU LONA IGBA O LE MERIN ATI EGBERUN LONA IRINWO O LE MEJIDINLAADOTA NAIRA (N2,204,448,000)

ETO IROYIN, IBANISORO ATI IMO ERO:

BILIONU KAN, MILIONU LONA ERINLELAADOFA, EGBERUN LONA ORINLELOODUNRUN O LE

MERIN ATI EEDEGBETA NAIRA (N1,106,468,500)

OKOOWO ATI ISE

BILIONU KAN, MILIONU LONA OTALELOGORUN O DIN MERIN AT EGBERUN LONA ORINLELEGBETA O

LE MEJO NAIRA (N1,156,688,000)

IRINA JO IMOLUKA

MILIONU LONA OODUNRUN O LE MOKANDINLAADOTA, EGBERUN LONA OTALELOODUNRUN O LE MEFA ATI

IRINWO NAIRA (#349,366,400)

AWON AKANSE ISE IJOBA MIRAN

BILIONU MERIN, MILIONU LONA MERINLELAADOTA, EGBERUN LONA OTALELEEDEGBERIN O LE MEJI ATI

OKANLELOGUN NAIRA (N4,054,762,021)

ETO EKO:

Page 12: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Project/Donor Approved 2020Budget

Revised 2020Budget

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 12

Bawo ni Ijoba Yoo Se Ri Owo Iranlowo Gba?

OWO IRANLOWO PATAKI FUN IJOBA IPINLE

BILIONU KAN, MILIONU MEJO,

EGBERUN LONA EEDEGBETA O LE

METALA ATI OKOOLELOODUNRUN

O DIN KAN NAIRA (1,008,513,319)

OWO IRANLOWO LATI ODO IJOBA APAPO

FUN AYIKA ATI AGBARA OJO

----

OWO IRANLOWO FUN ILE-IWE ALAKOBERE TI

A MO SI UBEC

BILIONU KAN, MILIONU MEJILA,

EGBERUN LONA ORINLELEGBETA

O LE MEJI ATI ERINLELEEDEGBERIN

NAIRA (1,012,682,704)

EYO OWO IDA KAN FUN ITOJU APO OWO

JAAC

MILIONU LONA IRINWO NAIRA

(400,000,000)

ETO GBIGBA OKAN MILIONU LA

MILIONU LONA OODUNRUN

NAIRA (300,000,000)

EYO OWO IDA KAN NINU OWO IJOBA IBILE

FUN YIYE IWE OWO

WO

MILIONU LONA IRINWO O LE

AADOTA, EGBERUN LONA

OJILENIGBA O DIN EYOKAN ATI

IRINWO O LE MOKANLELOGBON

NAIRA (450,239,431)

AKOJOPO OWO LATI ODO AWON A JO MDA

MILIONU LONA OTALENIGBA

NAIRA (260,000,000)

EYO OWO IDA KAN NINU OWO IJOBA IBILE

FUN IDANILEKO FUN AWO N OSISE IJOBA

IBILE

MILIONU LONA IGBA, EGBERUN

LONA OTALELEGBERIN O DIN

MEJO ATI EEDEGBERIN NAIRA

(200,852,700)

AKOJOPO OWO LATI AWON IJOBA IBILE

MILIONU LONA AADOJO NAIRA

(150,000,000)

AKOJOPO OWO LATI ODO AWON OLODANNI

ATI AWON ILE ISE NLANLA

MILIONU LONA AADOTA

(50,000,000)

OWO IRANLOWO LATI ODO AJO YESSO ATI

A JO AGBANISISE FUN IDANILEKO NI ILE EKO

OLORE TI IJOBA ORILE EDE YII ATI ILE KOREA

MILIONU LONA OGOJI NAIRA

(40,000,000)

OWO TI A FUN NI LATI ODO IJOBA APAPO

FUN ARUN KORONA

BILIONU KAN NAIRA

(1,000,000,000)

AKOJOPO OWO LATI ODO OLODANNI ATI

AWON ILE ISE NLANLA FUN ARUN KORONA

BILIONU KAN NAIRA

(1,000,000,000)

IRANLOWO LATI ODO AWON AJO

IDAGBASOKE FUN ARUN KORONA

MILIONU LONA EEDEGBETA NAIRA

(500,000,000)

Page 13: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi

N3.23bn

N3bn

N0.23bn

13

Bawo ni ijoba yoo se ri owo iranlowo gba?

Akojopo owo iranlowo lati okeere je:

Bilionu meta ati milionu lona metalelogun naira

Ajo teekoto fun ipinle ati ajo SFTAS fun abajade to peye

Bilionu meta naira

Ajo YESSO fun idanileko pelu

ajosepo KOICA-LOKOJA

Milionu lona metalelogun

Page 14: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi

N5.4bnOlufunni

Approved

Budget

Atunyewo

Isuna

14

Bawo ni Ijoba Yoo Se Ri

Eyawo Gba ?

AKOJOPO EYAWO L'ABELE JE

Bilionu marun ati milionu lona irinwo naira

Eyawo lati odo awon ile

ifowopamo fun ipinle Kogi

Bilionu meji naira

(2,000,000,000)

Eyawo fun ilegbee

Bilionu kan naira

(1,000,000,000)

Ajo to nri si Apo ifowosi,

idagbasoke ohun

amayederun ati ajo

olufunni lowo

-------

Mimu ounje asaraloore ya

kiakia lorileede Nigeria

Milionu lona

irinwo naira

(400,000,000)

Eyawo lati odo ile

ifowopamo ijoba apapo ati

awon ile ifowopamo miran

fun arun korona

Bilionu meji naira

(2,000,000,000)

Page 15: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

N2.91bn

Akanse Ise/Ile IseApproved

Budget

Atunyewo

Isuna

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 15

Bawo ni Ijoba Yoo Se

Ri Eyawo Gba ?

AKOJOPO EYAWO LATI OKEERE JE

Bilionu meji ati milionu

mokanle laadorun naira

Eyawo lati banki agbaye

lati fi seto ere oko ni ALAPE

Bilionu kan naira (1,000,000,000)

Iranlowo lati odo

banki

agbaye fun sise ojuna

igberiko ati itaja ohun

ogbin

Milionu lona

eedegbeta

(500,000,000)

Ajo NEW MAP

--------

Iranlowo lati odo banki

agbaye fun iseto ohun

ogbin ati igbe aye

Bilionu kan naira

(1,000,000,000)

Eto iranlowo banki agbaye

fun awon igberiko ati

nnkan amayederun

Milionu lona

oodunrun naira

(300,000,000)

Ajo YESSOMilionu lona aadofa

naira (110,000,000)

Page 16: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi

Government House 23,212,235,011 15,336,819,011

Deputy Governors Office 2,841,267,134 1,329,929,222

Office Of The Secretary To The State

Government 5,810,857,836 2,915,869,777

Kogi State House Of Assembly Service

Commission 6,595,634,518 8,535,873,681

Ministry Of Information And

Communication 1,508,605,793 3,501,993,014

Office Of The Head Of Civil Service 12,007,263,336 806,727,456

Office Of The State Auditor-general 1,164,236,829 714,569,604

Civil Service Commission 132,973,993 171,981,977

Local Government Service

Commission 387,125,968 4,742,075,832

Ministry Of Agriculture 11,455,059,911 10,362,489,026

Ministry Of Finance, Budget And

Economic Planning 17,925,492,167 892,437,567

Min. Of Commerce & Industry 1,959,926,025 442,810,964

Ministry Of Transport 1,216,135,581 6,204,082,634

Ministry Of Works And Housing 15,965,043,471 487,170,815

Min. Of Culture & Tourism 1,156,883,891 1,441,282,549

Ministry Of Water Resources 4,512,469,144 1,101,481,081

Bureau For Lands And Urban

Development 3,568,137,008 1,025,232,697

Ministry Of Rural Development 2,948,805,003 1,193,865,416

Kogi State Judicial Service

Commission 5,439,046,173 4,146,330,541

Ministry Of Justice 2,176,180,411 526,198,026

Ministry Of Youth & Sports 824,830,717 507,547,816

Ipin fun Eka

to ga/Ile Ise

Approved

Expenditure

Atunyewo Inawo

16

Ipinfuni Elekajeka

Olu ile ise ijoba

Bilionu meedogun, milionu lona

ojileloodunrun o din merin, egberun

lona okoolelegberin o dinkan ati naira

mokanla (15,336,819,011)

Ofiisi igbakeji gomina

Bilionu kan, milionu lona oodunrun o

le mokandinlogbon, egberun lona

eedegberun o le mokandinlogbon ati

okoolenigba o le meji naira

(1,329,929,222)

Ofiisi akowe fun ijoba

ipinle

Bilionu meji, milionu lona

eedegberun o le meedogun, egberun

lona otalelegberin o le mesan ati

orinleleedegberin o din meta naira

(2,915,869,777)

Ajo to nbojuto ile

igbimo asofin ipinle

Kogi

Bilionu mejo, milionu lona

ojileleedegbeta o din marun, egberun

lona orinlelegberin o din meje ati

orinlelegbeta o le eyokan naira

(8,535,873,681)

Ile ise iroyin/oro to nlo

ati ibanisoro

Bilionu meta, milionu lona

okanleleedegbeta, egberun lona

orinleleedegberun o le metala ati

naira merinla (3,501,993,014)

Ofiisi oga agba fun

awon osise ijoba

Milionu lona egberin o le mefa,

egberun lona okooleleedegberin o le

meje ati otalenirinwo o din merin

naira (806,727,456)

Ofiisi oluyeweowowo

agba fun ipinle

Milionu lona eedegberin o le merinl a,

egberun lona otaleleedegbeta o le

mesan ati erinlelegbeta naira

(714,569,604)

Ajo to n bojuto awon

osise ijoba

Milionu lona orinlelogorun o din

mesan, egberun lona

orinleleedegberun o lekan ati

orinleleedegberun o din meta naira

(171,981,977)

Page 17: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Ipinfuni Elekajeka

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 17

Ipin fun Eka

to ga/Ile Ise

Approved

Expenditure

Atunyewo Inawo

Ajo to nbojuto ijoba

ibile

Bilionu merin, milionu lona

ojileleedegberin o le meji, milionu

lona marundinlogorin ati

ojilelegberin o din mejo naira

(4,742,075,832)

Ile is eto ogbin Bilionu mewa, milionu lona

otaleloodunrun o le meji, egberun

lona orinlenirinwo o le mesan ati

naira merindinlogbon

(10,362,489,026)

Ile ise inawo, eto isuna

ati eto oro aje

Milionu lona orinlelegberin o le

mejila, egberun lona ojilenirinwo o

din meta ati otaleleedegbeta o le

meje naira (892,437,567)

Ile ise okoowo ati ise

Milionu lon a ijilenirinwo o le meji,

egberun lona egberin o le mewa ati

otaleleedegberun o le merin naira

(442,810,964)

Ile ise eto

irinna/igbokegbodo

Bilionu mefa, milionu lona

erinlenigba, egberun mejilelogorin ati

ojilelegbeta o din mefa naira

(6,204,082,634)

Ile ise ode ati ilegbee

Milionu lona orinlenirinwo o le meje,

egberun lona igba o din ogbon ati

okoolelegberin o din marun naira

(487,170,815)

Ile ise asa ati imoluka

Bilionu kan, milionu lona ojilenirinwo

o lekan, egberun lona orinlenigba o

lekan ati ojile leedegbeta o le mesan

naira (1,441,282,549)

Ile ise alumoni inu omi

Bilionu kan, milionu lona

okanlelogorun, egberun lona

orinlenirinwo o lekan ati naira

mokanlelogorin (1,101,481,081)

Ajo fun oro ile ati

idagbasoke ilu nlanla

Bilionu kan, milionu meedog bon,

egberun lona igba o le mejilelogbon

ati eedegberin o din meta naira

(1,025,232,697)

Page 18: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Ipinfuni Elekajeka

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 18

Ipin fun Eka

to ga/Ile Ise

Approved

Expenditure

Atunyewo Inawo

Ile ise idagbasoke

igberiko

Bilionu kan, milionu lona igba o din

meje, egberun lona otalelegberin o le

marun ati okoolenirinwo o din merin

naira (1,193,865,416)

Ajo to nbojuto eto

idajo ni ipinle Kogi

Bilionu merin, milionu lona

erindinlaadojo, egberun lona

ojileloodunrun o din mewa ati

ojileleedegbeta o lekan naira

(4,146,330,541)

Ile ise eto idajo

Milionu lona okooleleedegbeta o le

mefa, egberun lona igba o din meji ati

naira merindinlogbon (526,198,026)

Ile ise odo ati ere

idaraya

Milionu lona eedegbeta o le meje,

egberun lona ojileleedegbeta o le

meje ati okoolelegberin o din merin

naira (507,547,816)

Ile ise to nei si oro

awon obirin ati

idagbasoke ohun

amayederun

Bilionu metadinlogun, milionu lona

okooleleedegbeta, egberun lona

eedegbeta o din mefa ati eedegberin

o din merin naira (17,520,494,696)

Ile ise eto eko, imo

ijinle ati imo ero

Bilionu meedogun, milionu

merinlelaadota, egberun lona

otalenigba o din m erin ati

orinlelegberin o le metala naira

(15,054,256,893)

Ile ise eto ilera

Bilionu kan, milionu lona

okoolelegberin o le meta, egberun

lona orinleleedegbeta o le mefa ati

okanlenigba naira (1,823,586,201)

Ile ise eto ayika Milionu lona mokandinlaadorun ,

egberun lona okooleleedegberun o

din meta ati orinleleedegberun o

lekan naira (89,917,981)

Ile ise ijoba ibile ati oro

oye

Bilionu kan, milionu lona ojilenigba o

le mejo, egberun metadinlaadorin ati

otalenirinwo o din mefa naira

(1,248,067,454)

Page 19: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

AWON ISE AKANSE TI ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO/OGUN FOWOSI

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 19

Akanse Ise IbiRevised

ExpenditureAjo/Ile Ise Ijoba Ibile

Atunyewo

Iye Owo

Idasile ibudo

sise aayan ire

oko

ile ise eto

ogbin

Alape

Kabba Bunu

Bilionu kan ati

milionu lona

eedegbeta naira

(1,500,000)

Kiko ile iwosan

idarienisi ni

Okene

Ile ise eto

ilera

Okene

Okene

Bilionu meji ati

milionu lona

aadotaleleedegbeta

naira (2,550,000,000)

Kikapa agbara

ojo

Ile ise eto

ayika

Jakejado

ipinle

Jakejado ipinle

Milionu lona

eedegbeta naira

(500,000,000)

Rira oko fun

fun awon ile

ise ijoba ati

awon eka

Ofiisi oga

agba ni ile ise

ijoba

Olu ile ise

ijoba

Lokoja

Bilionu kan naira

(1,000,000,000)

Ipese omi fun

Lokoja nla apa

keji

Ile ise eto

ohun alumoni

inu omi

Olu ile ise

ijoba

Lokoja

Bilionu meji naira

(2,000,000,000)

Pipari

ibudo

iyeraeniwo ati

aworan ilera

igbalode pelu

awon irin ise

Ile ise eto

ilera

Olu ile ise

ijoba

Lokoja

Bilionu meji naira

(2,000,000,000)

Kiko ibi abo

fun isele ojiji ni

gbogbo awon

opopona

Pataki laarin

ipinle

Ile ise eto ise

ati ilegbee

Jakejado

ipinle

Jakejado ipinle

Bilionu kan ati

milionu lona

otalelegbeta o din

mewa naira

(1,650,000,000)

Isopo ijoba lori

ise akanseIle ijoba

Jakejado

ipinleJakejado ipinle

Bilionu kan ati

milionu lona

eedegbeta naira

(1,500,000,000)

Ajo to nboju

atunse awon

oju ona ni

ipinle Kogi

Ajo to n

bojuto oju

ona

Jakejado

ipinleJakejado ipinle

Milionu lona ogorun

naira (100,000,000)

Page 20: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa

Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 20

Akanse Ise IbiRevised

ExpenditureAjo/Ile Ise Ijoba Ibile

Atunyewo

Iye Owo

Atunko awon

iyara ikekoo ni

awon ile iwe

alakobere ati

awon ile iwe

giga

Ile ise eto eko,

sayensi ati

imo ero

Jakejado

ipinle

Jakejado ipinle

Milionu lona aadojo

naira (150,000,000)

Atunko ati fife

ayika ikekoo

ile iwe

mejilelogoji.

Meji fun ijoba

ibile kookan

(ogun ati

awose GYB)

Ile ise eto eko,

sayensi ati

imo ero

Jakejado

ipinle

Jakejado ipinle

Milionu lona ogorun

naira (100,000,000)

Ise akanse

elekunjekun

Ile igbimo

asofin ipinle

Kogi

Jakejado

ipinle

Jakejado ipinle

Milionu lona

eedegbeta naira

(500,000,000)

Owo Pataki

fun ajo eleto

idibo ipinle lati

seto idibo

ijoba ibile

Ajo eleto idibo

ipinle

Jakejado

ipinle

Jakejado ipinle

Milionu lona ogorun

naira (100,000,000)

Ituyayajade

akanse ise

ogbin ni ipinle

Kogi

Ile ise eto

ogbin

Jakejado

ipinle

Jakejado ipinle

Milionu lona ogorun

naira (100,000,000)

Awon ona ti a

sa yan ni ekun

aarin

gbungbun

asojusofin

Ile ise eto ise

ati ilegbee

Ekun aarin

gbungbun

asojusofin

Okene, Okehi,

Adavi, Ajaokuta

ati

Ogori/Magongo

Bilionu kan naira

Igbesoke ile

ise amunawa

fun awon ijoba

ibile ati

igberiko

Ile ise eto

idagbasoke

igberiko

Ekun ila

oorun

asojusofin

Idah, Ankpa,

Ibaji, Ofu,

Olamaboro,

Omala, Dekina,

Igalamela ati

Bassa

Milionu lona

merinlelogorun ati

egberun lona egberin

naira (104,800,000)

Page 21: ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN EGBAA O LE OKOO / OGUN · 2020. 9. 27. · ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI 15-18. Oro Akoso Atunyewo Eto Isuna Awa