Four Laws [Gospel Tract] - Yoruba Language

Embed Size (px)

Citation preview

  • 8/2/2019 Four Laws [Gospel Tract] - Yoruba Language

    1/5

    Yoruba/ English Edition - Page 1

    Nj O Ti Gb Nipa fin Mrin Ti Emi?

    Have You Heard of the Four Spiritual Laws?

    God LOVES you and offers a

    wonderful PLAN for your life.

    This is

    GODS LOVE

    God so loved the world that He gave His one andonly Son, that whoever believes in Him shall not

    perish, but have eternal life (John 3:16 NIV).

    And

    GODS PLAN

    [Christ speaking] I came that they might have life,and might have it abundantly (John 10:10) [thatit might be full and meaningful] .

    Why is it that most people are not experiencing theabundant life?

    Just as there are physical laws that govern the physicaluniverse, so are there spiritual laws which govern yourrelationship with God.

    Man is SINFUL and SEPARATED

    from God. Thus, he cannot know and

    experience Gods love and plan for his

    life.

    MAN IS SINFUL

    All have sinned and fall short of the glory of God(Romans 3:23).

    Man was created to have fellowship with God; but,because of his stubborn self-will, he chose to go his ownindependent way, and fellowship with God was broken.This self-will, characterized by an attitude of activerebellion or passive indifference, is an evidence of whatthe Bible calls sin.

    "We all, like sheep, have gone astray, each of ushas turned to his own way" Isaiah 53:6)

    lrun FRANFRANFRANFRANFRAN r, O si ni ETOETOETOETOETOrere fun aye r

    Eyi ni

    IF LRUNIF LRUNIF LRUNIF LRUNIF LRUN

    "Nitori lrun f araiye to b g, ti o fi mo bibi rkanoo funni, ki nikni ti o ba gb a gb m bsegb, sugbn ki o le ni iye ainipkun"(Johannu 3:16).

    Ati

    ETO LRUNETO LRUNETO LRUNETO LRUNETO LRUN[Kristi wipe] Emi wa ki nwn le ni iye, ani kinwn le nii lplp (Johannu 10:10). [Itumeyi ni: Igbesiaiye kikun, ti o ni tlrn].

    Ki ie gbogbo enia lo ngbe igbesiaiye to kun to si ni

    tlrn nitoripe

    ENIA J LSENIA J LSENIA J LSENIA J LSENIA J LS

    Gbogbo enia li o s ti s, ti nwn si kuna ogolrun (Romu 3:23).

    lrun da enia ki a le ni irp tmtm plu R;sugbn awa enia yn lati b Ona tiwa l, irpplu lrun si ja. Tt si na ti ara wa ibase ninuohun kekere tabi ohun nla j s. r lrun lo sb.

    "Gbogbo wa ti sina kkiri bi aguntan,olukuluku wa tle na ara r" (Isaiah 53:6)

    Awa enia j L,L,L,L,L, a si ti YYYYYAPAPAPAPAPAAAAAkuro ld lrun, nitorina a ko le mif lrun, bni a ko le ni rr eto rfun igbesiaiye wa.

    Bi ijba wa ti ni awn ofin lati bojuto alafia ilu, bni

    Olrun ni awn ofin ti a nilati m, bi a ba f ni alafia plu

  • 8/2/2019 Four Laws [Gospel Tract] - Yoruba Language

    2/5

    Yoruba/ English Edition - Page 2

    .

    MAN IS SEPARATED

    The wages of sin is death [spiritual separation fromGod] (Romans 6:23).

    This diagram illustrates that God isholy and man is sinful. A great gulfseparates the two. The arrowsillustrate that man is continuallytrying to reach God and theabundant life through his ownefforts, such as a good life,philosophy, or religion but heinevitably fails.

    The third law explains the only way to bridge this gulf...

    Nipas Jesu Kristi nikansoso ni ale de d lrun. O ku fun wa.Nipas Jesu nikan ni o le m iflrun. Iw y si ni iriri eto lrunni igbesiaiye r.

    O KU DIPO WO KU DIPO WO KU DIPO WO KU DIPO WO KU DIPO WAAAAA

    ugbn lrun fi if On papa si wa han ni eyipe, nigbati awa j ls, Kristi ku fun wa(Romu 5:8)

    O JI DIDE NINU OKUO JI DIDE NINU OKUO JI DIDE NINU OKUO JI DIDE NINU OKUO JI DIDE NINU OKU

    Kristi ti ku nitori s wa a sinku r O jindeni ij kta ggbi iwemim ti wi (Korinti 15:3-4)

    JESU NI NA KANOO N JESU NI NA KANOO N JESU NI NA KANOO N JESU NI NA KANOO N JESU NI NA KANOO N

    Jesu wi fun u pe, Emi li na, ati Otit ati iye:k si nikni ti o le w sd Baba, bikose nipasmi (Johannu 14:6).

    Aworan yi fihan wipe lrun nikanni o le mu wa pada sd ara R.lrun se eyi nipa riran Jesu Kristilati ku ni ori igi agbelebu fun wa.

    ugbn ko to fun wa lati m awn ofin m ta yi nikan

    Jesus Christ is Gods ONLY provision

    for mans sin. Through Him you can

    know and experience Gods love and

    plan for your life.

    HE DIED IN OUR PLACE

    God demonstrates His own love toward us, in thatwhile we were yet sinners, Christ died for us(Romans 5:8).

    HE ROSE FROM THE DEAD

    Christ died for our sinsHe was buried He wasraised on the third day, according to the Scriptures.(1 Corinthians 15:3,4).

    HE IS THE ONLY WAY TO GOD

    Jesus said to him, I am the way, and the truth,and the life; no one comes to the Father, but through

    Me (John 14:6).

    This diagram illustrates thatGod has bridged the gulf whichseparates us from Him bysending His Son, Jesus Christ,to die on the cross in our placeto pay the penalty for our sins.

    It is not enough just to know these three laws

    IYIYIYIYIYAPAPAPAPAPAAAAA WWWWWAAAAA L'ARIN ENIAL'ARIN ENIAL'ARIN ENIAL'ARIN ENIAL'ARIN ENIA AAAAATI LRUNTI LRUNTI LRUNTI LRUNTI LRUN

    "Nitori iku li re "[Itum eyi ni, iyapa ti mikuro ld lrun] (Romu 3:23)

    Aworan yi fihan wipe, nitori lrunj mim enia j ls, iyapa nla wlrin awn mejji. Aworan yi seapejuwe pe enia ngbiyanju lati ded lrun. A lero pe bi a ba s

    sin dada, tabi ki a j enia rere,ki a ma gbadura, ki a ma l si ilelrun (i), bi a ko ba se ibi sinikeji wa, ati bb l, a o ded lrun. ugbn asan nigbogb iyanju yi.

    Ofin kta ntka si n kanoo ti a le gba pada s'dlrun

    SINFUL MAN

    AWA ENIA ELEE

    HOLY GOD

    LRUN MIM

    JJJJJEEEEESSSSSUUUUU

    SINFUL MAN

    ENIAENIAENIAENIAENIA

    HOLY GOD

    lrunlrunlrunlrunlrun

  • 8/2/2019 Four Laws [Gospel Tract] - Yoruba Language

    3/5

    Yoruba/ English Edition - Page 3

    We must individually RECEIVE Jesus

    Christ as Saviour and Lord; then we can

    know and experience Gods love and

    plan for our lives.

    WE MUST RECEIVE CHRIST

    As many as received Him, to them He gave theright to become children of God, even to those whobelieve in His name (John 1:12)

    By grace you have been saved through faith; andthat not of yourselves, it is the gift of God; not as aresult of works, that no one should boast(Ephesians 2:8,9).

    WE RECEIVE CHRIST THROUGH

    PERSONAL INVITATION

    [Christ speaking] Behold, I stand at the door andknock; if any one hears My voice and opens the door,

    I will come in to him (Revelation 3:20).

    Receiving Christ involves turning to God from self(repentance) and trusting Christ to come into our lives toforgive our sins and to make us what He wants us to be.Just to agree intellectually that Jesus Christ is the Son ofGod and that He died on the cross for our sins is not enough.Nor is it enough to have an emotional expereince. Wereceive Jesus Christ by faith, as an act of the will.

    These two circles represent two kinds oflives:

    SELF-DIRECTED LIFE

    Self is on the throne. Christ is outside the

    life. Interests are directed by self, often

    resulting in discord and frustration

    CHRIST-DIRECTED LIFE

    Christ is in the life and on the throne. Selfis yielding to Christ. Interests are directed

    by Christ, resulting in harmony with God's

    plan.

    Which circle best represents your life?

    Which circle would you like to have represent yourlife?

    The following explains how you can receive Christ...

    Eni kkan wa ni LALALALALATITITITITI gba JesuKristi ni Olugbala ati Oluwa. Nigbayini a to le m if lrun, ti a si le ni iririeto r fun igbesiaiye wa.

    AAAAA NI LANI LANI LANI LANI LATI GBATI GBATI GBATI GBATI GBA KRISTI NIPKRISTI NIPKRISTI NIPKRISTI NIPKRISTI NIPAAAAA IGBAGBIGBAGBIGBAGBIGBAGBIGBAGBSugbn iye awon ti o gba a, awn li a fi agbarafun lati di m lrun, ani awn na ti o gboruk r gb. (Johannu 1:12).

    Nitori ore-f li a ti fi gba nyin l nipa igbagbki ie nipa i ki nikni m ba ogo.(Efesu 2:8,9).

    AAAAANI LANI LANI LANI LANI LATI GBATI GBATI GBATI GBATI GBAKRISTI NIPKRISTI NIPKRISTI NIPKRISTI NIPKRISTI NIPAAAAAPIPE E FUNPIPE E FUNPIPE E FUNPIPE E FUNPIPE E FUN ARAARAARAARAARAWWWWWAAAAA

    [Kristi wipe] Kiyesi i, mo duro li enu ilkun (kanr), mo si nknkun, bi nikni ba gb Ohun mi,

    ti o si si Ilkun, emi o si wle t wa(Ifihan 3:20).

    Itum gbigba Kristi ni wipe, ki a ni igbkl ninulrun lati wa si inu igbesiaiye wa, ki O si dari swa j wa; ki a yipada kuro ninu s wa, ki a si j kiKristi wa gbe igbesiaiye R ninu wa.

    Awn aworan meji yi nse apejuwe orisi igbesiaiye meji:

    IGBESIAIYE ENIIGBESIAIYE ENIIGBESIAIYE ENIIGBESIAIYE ENIIGBESIAIYE ENI TI NTI NTI NTI NTI NEEEEE AKOSOAKOSOAKOSOAKOSOAKOSO ARAREARAREARAREARAREARARE

    Eni yi ndari aiye ara r. Kristi () wa lode aiye yi.Awn m dudu yi, duro fun orisirisi nynigbesiaiye yi, ggbi, sn, owo, s, sro, atibb l ti ni yi ndari. ugbn sibsib ni yi koni ifkanbal t p.

    IG BESIAIYEBESIAIYEBESIAIYEBESIAIYEBESIAIYE TI KRISTI NSETI KRISTI NSETI KRISTI NSETI KRISTI NSETI KRISTI NSE AKOSO REAKOSO REAKOSO REAKOSO REAKOSO RE

    Nibiyi, Kristi () ti w inu igbesiaiye ni yi lati darir. ni yi jw aniyan aiye r fun Kristi lati darianiyan ggbi, sn, owo, s, sro, ati bb l.Eni yi ni ifkanbal plu lrun.

    AAAAAworan wo lo j igbesiaiye r?woran wo lo j igbesiaiye r?woran wo lo j igbesiaiye r?woran wo lo j igbesiaiye r?woran wo lo j igbesiaiye r?

    Aworan wo lo fe ki igbesiaiye r?Aworan wo lo fe ki igbesiaiye r?Aworan wo lo fe ki igbesiaiye r?Aworan wo lo fe ki igbesiaiye r?Aworan wo lo fe ki igbesiaiye r?

    Eyi ni ly bi o ti se le gba Kristi

    S

    YS

  • 8/2/2019 Four Laws [Gospel Tract] - Yoruba Language

    4/5

    Yoruba/ English Edition - Page 4

    YOU CAN RECEIVE CHRIST RIGHT NOW BY

    FAITH THROUGH PRAYER

    God knows your heart and is not so concerned with yourwords as He is with the attitude of your heart. Thefollowing is a suggested prayer:

    Lord Jesus, I need You. Thank You for dying

    on the cross for my sins. I open the door of my

    life and receive You as my Savior and Lord.Thank You for forgiving my sins and giving me

    eternal life. Take control of the throne of my life.

    Make me the kind of person You want me to be.

    Amen.

    Does this prayer express the desire of your heart?

    If it does, I invite you to pray this prayer right now, andChrist will come into your life, as He promised.

    Did you receive Christ into your life? According to His

    promise in Revelation 3:20, where is Christ right now inrelation to you? Christ said that He would come into yourlife. Would He mislead you? On what authority do youknow that God has answered your prayer?

    DON'T RELY ON FEELINGS

    Thank God often that Christ is in your life and that Hewill never leave you (Hebrews 13:5). You can know onthe basis of His promise that Christ lives in you and thatyou have eternal life from the very moment you inviteHim in. He will not deceive you.

    The moment that you received Christ by faith, as an actof the will, many things happened, including thefollowing:

    1. Christ came into your life (Revelation 3:20).

    2. Your sins were forgiven (Colossians 1:14).

    3. You became a child of God (John 1:12).

    4. You received eternal life (John 5:11-13)

    5. You began the great adventure for which God createdyou (John 10:10, 2 Corinthians 5:17).

    Can you think of anything more wonderful that couldhappen to you than receiving Christ? Would you like tothank God in prayer right now for what He has done foryou? By thanking God, you demonstrate your faith.

    O LE GBAO LE GBAO LE GBAO LE GBAO LE GBA KKRISTI NISISIYI NIPKKRISTI NISISIYI NIPKKRISTI NISISIYI NIPKKRISTI NISISIYI NIPKKRISTI NISISIYI NIPAAAAAIGBAGBIGBAGBIGBAGBIGBAGBIGBAGB

    O le gba Kristi ni Olugbala ati Oluwa bi o ba gbadurape ki Kristi w inu igbesiaiye r wa. Ki o ni igbagbpe yio wa. Adura yi ni lati j tkantkan. lrun mkan r, o ko si le tan A j. Gba iru adura bayi:

    "Jesu Oluwa, mo m wipe emi ni mo ti"Jesu Oluwa, mo m wipe emi ni mo ti"Jesu Oluwa, mo m wipe emi ni mo ti"Jesu Oluwa, mo m wipe emi ni mo ti"Jesu Oluwa, mo m wipe emi ni mo ti

    ndari aiye mi. Nitori eyi, mo ti ds si .ndari aiye mi. Nitori eyi, mo ti ds si .ndari aiye mi. Nitori eyi, mo ti ds si .ndari aiye mi. Nitori eyi, mo ti ds si .ndari aiye mi. Nitori eyi, mo ti ds si .Jw wa sinu aiye mi, wa dari mi jJw wa sinu aiye mi, wa dari mi jJw wa sinu aiye mi, wa dari mi jJw wa sinu aiye mi, wa dari mi jJw wa sinu aiye mi, wa dari mi jmi. Wmi. Wmi. Wmi. Wmi. Wa ea ea ea ea e Alakoso igbesiaiye mi. S miAlakoso igbesiaiye mi. S miAlakoso igbesiaiye mi. S miAlakoso igbesiaiye mi. S miAlakoso igbesiaiye mi. S midi ni mim. Mo dup pe, O ti gb aduradi ni mim. Mo dup pe, O ti gb aduradi ni mim. Mo dup pe, O ti gb aduradi ni mim. Mo dup pe, O ti gb aduradi ni mim. Mo dup pe, O ti gb adurami.mi.mi.mi.mi . Amin.Amin.Amin.Amin.Amin.

    Nj o f lati gba adura yi?

    Bi o ba f b, gba adura yi nisisiyi, Jesu yio si wasinu igbesiaiye r ggbi O ti e ileri.

    Nj o ti gba Kristi sinu aiye r? Bawo ni o e m?

    Boju wo hin lati ri ileri Kristi ni Ifihan 3:20 A le mwipe Kristi wa ninu aiye wa nitoriwipe Kristi e ilerilati w. O k tun ni lati pe Kristi wle m.

    MAE GBOJULE ERO KAN REMAE GBOJULE ERO KAN REMAE GBOJULE ERO KAN REMAE GBOJULE ERO KAN REMAE GBOJULE ERO KAN RE

    Inu r le dun Ioni, Kristi yio siwa sinu igbesiaiye r.Kristi wipe, Emi ko j fi sil (Heberu 13:5). Klati ma gbkle awn ileri lrun, ma gbkle erokan r.

    Nigbati o gba kristi plp nkan ni o lDi ninu wn niwnyi:-

    1. Kristi wa si inu igbesiaiye r (Ifihan 3:20)

    2. A dari r ji (Kolose 1:14).

    3. O di m lrun(Johannu 1:12).

    4. O ni y ainipkun (1Johannu 5:11-1 3).

    5. O br si ni iriri igbesiaiye titun ti o niitlrun bi kKristi ti ngbe igbesiaiye R ninu

    r (Johannu 10:10; 2 Korinti 5:17).

    p lr bayi ati ju b l lati inu r lrun ni nwnje tir. Y nwn wo ninu Bibeli. Ni Ise-Awn-Apsteli 17:11 nwn ny Iwe Mim w lojojum "binkan wnyi ri b.

  • 8/2/2019 Four Laws [Gospel Tract] - Yoruba Language

    5/5

    Yoruba/ English Edition - Page 5

    Helping you reach multicultural

    communities with the Gospel

    Campus Crusade For Christ ti Nigeria,

    PO Box 500, Jos.

    Gods Word instructs us not to forsake the assembling of

    ourselves together (Hebrews 10:25).Start going to churchwhere Christ is honoured and His Word is preached. Startthis week, and make plans to attend regularly.

    Why not share this message with someone else?

    O se pataki pe ki o darap m awn onigbagb fun

    idagbasoke ninu igbagb r (Heberu 10:25). Brsi l si ile lrun ti nwn ti mbu la fun Kristi, ti nwnsi nwasu otit r R.

    Ko wa y ki o fi irohin ay yi l lomiran?Ko wa y ki o fi irohin ay yi l lomiran?Ko wa y ki o fi irohin ay yi l lomiran?Ko wa y ki o fi irohin ay yi l lomiran?Ko wa y ki o fi irohin ay yi l lomiran?

    IMIMIMIMIMRAN FUN IDAGBEASOKE NINURAN FUN IDAGBEASOKE NINURAN FUN IDAGBEASOKE NINURAN FUN IDAGBEASOKE NINURAN FUN IDAGBEASOKE NINUIGBAGBIGBAGBIGBAGBIGBAGBIGBAGB

    Ma gba dura lojojum (Luku 18:1).

    Ma ka r lrun (Bibeli) lojojum(Orin Dafidi 119:11) Br si k lati inu ehinrere tiJohannu.

    Ma se igboran si lrun nigbagbogbo(Johannu 14:21).

    Ma jri fun Kristi nipa igbesiaiye r ati r nu r(Luku 8:39).

    Ma gbkele lrun ninu ohun gbogbo (1 Peteru 5:7).

    Ma je ki Emi Mim lrun ti O wa ninu r nisisyidari igbesiaiye r. J ki O fun ni agbara lati jriJesu (Galatia 5:16,17; Ie Awn Apsteli 1:8).

    SUGGESTIONS FOR CHRISTIAN GROWTH

    Go to God in prayer daily (Luke 18:1).

    Read Gods Word daily (Ps 119:11); begin with the Gospelof John.

    Obey God moment by moment (John 14:21).

    Witness for Christ by your life and words

    (Luke 18:39).

    Trust God for every detail of your life (1 Peter 5:7).

    Holy Spirit - allow Him to control and empower yourdaily life and witness (Galatians 5:16,17; Acts 1:8).

    SPECIAL MATERIALS ARE AVAILABLE FOR

    CHRISTIAN GROWTH.

    If you have come to Christ personally through thispresentation of the gospel, helpful materials for Christiangrowth are available to you. For more information write:

    Campus Crusade for Christ Australia,PO Box 40,Sydney Markets, NSW 2129

    phone (02) 9748 5798 Fax: (02) 9748 5799email: [email protected]: www.hereslife.com

    Campus Crusade for Christ Australia, 2002A.C.N. 002 310 796 Item: YorEng4pWBw05Apr