Owonrin sogbe

Embed Size (px)

Citation preview

Owonrin sogbeOlu kinndirinAsa kinndirinAdifafun OwonrinTi n sawo lo apa OkunO nloo gbgn OkunO nloo gbgn IdeO nloo gbgn aso Ologiningin daso Irada waleEbo ni ko waa seOgbebo oruboOlu kinndirinEsu Owonrinsogbe paya waOlu kinndirinEsu Owonrinsogbe paje waOlu kinndirinEsu Owonrinsogbe pomo waOlu kinndirinEsu Owonrinsogbe pogbo waOlu kinndirinEsu Owonrinsogbe pre gbogbo wa

Owonrin sogbeBnrahun Awo OdeOpe gorongobi awo ijesaErigi dudu awo imosakunAdifafun Olofin obelenjeTi nba ibi i sunTi nba ibi i jiEbo lori waseOgbebo oruboOni ki ibi diIbi a o mo yaa loIgba lewe Olowaransasan okoKa si ko rebi elujuA kore soju AwoAlubi a si da epeyin daEdu gbaleoEdu gbonaEdu gba irunbi gbogbo da sosa